Lefitiku 16:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ó fa ewúrẹ́ náà tọ Asaseli lọ ninu aṣálẹ̀ yóo fọ aṣọ rẹ̀, yóo sì wẹ̀, lẹ́yìn náà, ó lè wọ ibùdó.

Lefitiku 16

Lefitiku 16:16-28