Lefitiku 16:23 BIBELI MIMỌ (BM)

“Aaroni yóo pada wá sinu Àgọ́ Àjọ, yóo bọ́ àwọn aṣọ funfun tí ó wọ̀ kí ó tó wọ inú ibi mímọ́ lọ, yóo sì fi wọ́n sílẹ̀ níbẹ̀.

Lefitiku 16

Lefitiku 16:19-25