Lefitiku 16:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí meji ninu àwọn ọmọ Aaroni kú, nígbà tí wọ́n fi iná tí kò mọ́ rúbọ sí OLUWA, OLUWA bá sọ fún Mose pé,

Lefitiku 16

Lefitiku 16:1-6