Lefitiku 15:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohunkohun tí ó bá dùbúlẹ̀ lé lórí, tabi tí ó jókòó lé lórí ní gbogbo àkókò àìmọ́ rẹ̀ yóo di aláìmọ́.

Lefitiku 15

Lefitiku 15:19-30