Lefitiku 14:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn yóo wá wá àwọn òkúta mìíràn, wọn yóo fi dípò àwọn tí wọ́n yọ kúrò, yóo sì fi ohun ìrẹ́lé mìíràn tún ilé náà rẹ́.

Lefitiku 14

Lefitiku 14:34-49