Lefitiku 14:19 BIBELI MIMỌ (BM)

“Alufaa yóo rú ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ láti ṣe ètùtù fún ẹni tí wọ́n fẹ́ sọ di mímọ́, lẹ́yìn náà, yóo pa ẹran ẹbọ sísun náà.

Lefitiku 14

Lefitiku 14:14-22