Lefitiku 13:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ keje, alufaa náà yóo yẹ abirùn náà wò, bí àrùn náà kò bá tàn káàkiri ara rẹ̀, kí alufaa tún tì í mọ́lé fún ọjọ́ meje sí i.

Lefitiku 13

Lefitiku 13:1-12