Lefitiku 13:46 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo jẹ́ aláìmọ́, níwọ̀n ìgbà tí àrùn yìí bá wà lára rẹ̀. Ó jẹ́ aláìmọ́; òun nìkan ni yóo sì máa dá gbé lẹ́yìn ibùdó.

Lefitiku 13

Lefitiku 13:45-50