Lefitiku 13:39 BIBELI MIMỌ (BM)

kí alufaa yẹ̀ ẹ́ wò, bí ọ̀gangan ibẹ̀ bá funfun díẹ̀ tí ó dúdú díẹ̀, ara olúwarẹ̀ kàn fín lásán ni, ó mọ́.

Lefitiku 13

Lefitiku 13:29-45