Lefitiku 13:33 BIBELI MIMỌ (BM)

kí ó fá irun orí tabi ti àgbọ̀n olúwarẹ̀, ṣugbọn kí ó má fá irun ọ̀gangan ibi tí ẹ̀yi náà wà. Kí alufaa tún ti ẹni náà mọ́lé fún ọjọ́ meje sí i.

Lefitiku 13

Lefitiku 13:27-35