Lefitiku 13:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí àmì yìí kò bá paradà níbi tí ó wà, tí kò sì tàn káàkiri, àpá oówo lásán ni, kí alufaa pe ẹni náà ní mímọ́.

Lefitiku 13

Lefitiku 13:19-32