Lefitiku 13:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn tí egbò yìí bá jiná, tí ojú rẹ̀ pada di funfun, kí ẹni náà pada tọ alufaa lọ.

Lefitiku 13

Lefitiku 13:15-18