Lefitiku 11:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Tí ó bá jẹ́ odò, tabi kànga tí ó ní omi ni, wọn kì í ṣe aláìmọ́, ṣugbọn gbogbo nǹkan yòókù tí ó fara kan òkú wọn di aláìmọ́.

Lefitiku 11

Lefitiku 11:28-38