Lefitiku 1:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, kí àwọn ọmọ Aaroni, alufaa, to àwọn igẹ̀ ẹran náà ati orí rẹ̀ ati ọ̀rá rẹ̀ sórí igi tí wọ́n dáná sí, lórí pẹpẹ náà.

Lefitiku 1

Lefitiku 1:1-14