Lefitiku 1:16 BIBELI MIMỌ (BM)

kí ó fa àjẹsí rẹ̀ yọ, kí ó sì tu ìyẹ́ rẹ̀, kí ó dà á sí apá ìhà ìlà oòrùn pẹpẹ náà, níbi tí wọn ń da eérú sí.

Lefitiku 1

Lefitiku 1:8-17