Lefitiku 1:14 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ó bá jẹ́ pé ẹyẹ ni eniyan bá fẹ́ fi rú ẹbọ sísun, kí ó mú àdàbà tabi ọmọ ẹyẹlé wá.

Lefitiku 1

Lefitiku 1:4-16