Kronika Kinni 9:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, àwọn ati àwọn ọmọ wọn ni wọ́n ń ṣe alabojuto ẹnu ọ̀nà ilé OLUWA, àwọn ni wọ́n fi ṣe olùṣọ́ Àgọ́ Àjọ.

Kronika Kinni 9

Kronika Kinni 9:16-26