Kronika Kinni 9:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Lefi tí wọn ń gbé Jerusalẹmu nìwọ̀nyí: Ṣemaaya ọmọ Haṣihubu, ọmọ Asirikamu, ọmọ Haṣabaya, lára àwọn ọmọ Merari;

Kronika Kinni 9

Kronika Kinni 9:4-23