Kronika Kinni 8:34-37 BIBELI MIMỌ (BM)

34. Jonatani bí Meribibaali, Meribibaali sì bí Mika.

35. Mika bí ọmọkunrin mẹrin: Pitoni, Meleki, Tarea ati Ahasi.

36. Ahasi ni baba Jehoada. Jehoada sì ni baba: Alemeti, Asimafeti, ati Simiri. Simiri ni ó bí Mosa.

37. Mosa bí Binea; Binea bí Rafa, Rafa bí Eleasa, Eleasa sì bí Aseli.

Kronika Kinni 8