Kronika Kinni 8:22-28 BIBELI MIMỌ (BM)

22. Àwọn ọmọ Ṣaṣaki nìwọ̀nyí: Iṣipani, Eberi, ati Elieli;

23. Abidoni, Sikiri, ati Hanani;

24. Hananaya, Elamu, ati Antotija;

25. Ifideaya ati Penueli.

26. Àwọn ọmọ Jerohamu ni: Ṣamṣerai, Ṣeharaya, ati Atalaya;

27. Jaareṣaya, Elija ati Sikiri.

28. Àwọn ni baálé baálé ní ìdílé wọn, ìjòyè ni wọ́n ní ìran wọn; wọ́n ń gbé Jerusalẹmu.

Kronika Kinni 8