Kronika Kinni 8:18-25 BIBELI MIMỌ (BM)

18. Iṣimerai, Isilaya ati Jobabu.

19. Àwọn ọmọ Ṣimei ni: Jakimu, Sikiri, ati Sabidi;

20. Elienai, Siletai, ati Elieli;

21. Adaaya, Beraaya ati Ṣimirati;

22. Àwọn ọmọ Ṣaṣaki nìwọ̀nyí: Iṣipani, Eberi, ati Elieli;

23. Abidoni, Sikiri, ati Hanani;

24. Hananaya, Elamu, ati Antotija;

25. Ifideaya ati Penueli.

Kronika Kinni 8