Kronika Kinni 8:18-22 BIBELI MIMỌ (BM)

18. Iṣimerai, Isilaya ati Jobabu.

19. Àwọn ọmọ Ṣimei ni: Jakimu, Sikiri, ati Sabidi;

20. Elienai, Siletai, ati Elieli;

21. Adaaya, Beraaya ati Ṣimirati;

22. Àwọn ọmọ Ṣaṣaki nìwọ̀nyí: Iṣipani, Eberi, ati Elieli;

Kronika Kinni 8