Kronika Kinni 8:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Elipaali bí ọmọkunrin mẹta: Eberi, Miṣamu ati Ṣemedi. Ṣemedi yìí ni ó kọ́ àwọn ìlú Ono, Lodi, ati gbogbo àwọn ìletò tí ó yí wọn ká.

Kronika Kinni 8

Kronika Kinni 8:6-22