Kronika Kinni 7:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Àkọsílẹ̀ ìran wọn ní ìdílé, àwọn baálé baálé ní ilé baba wọn, tí wọ́n jẹ́ akọni jagunjagun, gbogbo wọn jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ati igba (20,200).

Kronika Kinni 7

Kronika Kinni 7:4-11