Kronika Kinni 7:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, Efuraimu bá aya rẹ̀ lòpọ̀, ó lóyún, ó sì bí ọmọkunrin kan. Ó sọ ọmọ náà ní Beraya nítorí ibi tí ó dé bá ìdílé wọn.

Kronika Kinni 7

Kronika Kinni 7:17-30