Kronika Kinni 7:21 BIBELI MIMỌ (BM)

baba Sabadi, baba Ṣutela, Eseri, ati Eleadi; Eseri ati Eleadi yìí ni àwọn ará ìlú Gati pa nígbà tí wọ́n lọ kó ẹran ọ̀sìn àwọn ará Gati.

Kronika Kinni 7

Kronika Kinni 7:17-30