Kronika Kinni 7:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Manase fẹ́ obinrin kan, ará Aramea; ọmọ meji ni obinrin náà bí fún un; Asirieli, ati Makiri, baba Gileadi.

Kronika Kinni 7

Kronika Kinni 7:8-22