Kronika Kinni 7:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo wọn jẹ́ ọmọ Jediaeli; àwọn tí wọ́n jẹ́ baálé baálé ní ilé baba wọn ati akọni jagunjagun ninu ìran wọn tó ẹẹdẹgbaasan-an ó lé igba (17,200).

Kronika Kinni 7

Kronika Kinni 7:5-12