Kronika Kinni 6:67 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ìlú ààbò tí wọ́n fún wọn, pẹlu àwọn pápá oko tí ó yí wọn ká, ní agbègbè olókè Efuraimu nìwọ̀nyí; Ṣekemu, ati Geseri;

Kronika Kinni 6

Kronika Kinni 6:63-70