Kronika Kinni 6:57 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Aaroni ni a pín àwọn ìlú ààbò wọnyi fún: Heburoni, Libina, Jatiri ati Eṣitemoa, pẹlu àwọn pápá oko tí ó yí wọn ká.

Kronika Kinni 6

Kronika Kinni 6:47-67