Kronika Kinni 6:54 BIBELI MIMỌ (BM)

Ilẹ̀ tí a pín fún ìran Aaroni nìyí, pẹlu ààlà wọn: ìdílé Kohati ni a kọ́kọ́ pín ilẹ̀ fún ninu àwọn ọmọ Lefi.

Kronika Kinni 6

Kronika Kinni 6:50-58