Kronika Kinni 6:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Asafu, arakunrin rẹ̀, ni olórí àwọn ẹgbẹ́ akọrin tí ń dúró ní apá ọ̀tun rẹ̀. Asafu yìí jẹ́ ọmọ Berekaya, ọmọ Ṣimea;

Kronika Kinni 6

Kronika Kinni 6:33-40