Kronika Kinni 5:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ilẹ̀ wọn lọ ní apá ìlà oòrùn títí dé àtiwọ aṣálẹ̀, ati títí dé odò Yufurate, nítorí pé ẹran ọ̀sìn wọn pọ̀ ní ilẹ̀ Gileadi.

Kronika Kinni 5

Kronika Kinni 5:1-18