Kronika Kinni 5:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn ẹ̀yà náà ṣẹ Ọlọrun baba wọn, wọ́n pada lẹ́yìn rẹ̀, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí bọ àwọn oriṣa tí àwọn tí Ọlọrun parun nítorí wọn ń bọ.

Kronika Kinni 5

Kronika Kinni 5:17-26