Kronika Kinni 4:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin kan, tí à ń pè ní Jabesi, jẹ́ eniyan pataki ju àwọn arakunrin rẹ̀ lọ. Ìyá rẹ̀ sọ ọ́ ní orúkọ yìí nítorí ìrora pupọ tí ó ní nígbà tí ó bí i.

Kronika Kinni 4

Kronika Kinni 4:2-16