Kronika Kinni 4:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹẹdẹgbẹta (500) ninu àwọn eniyan Simeoni ló lọ sí òkè Seiri; àwọn olórí wọn ni: Pelataya, Nearaya, Refaaya, ati Usieli, lára àwọn ọmọ Iṣi.

Kronika Kinni 4

Kronika Kinni 4:40-43