Kronika Kinni 4:34-36 BIBELI MIMỌ (BM)

34. Meṣobabu, Jamileki, ati Joṣa, jẹ́ ọmọ Amasaya;

35. Joẹli, ati Jehu, ọmọ Joṣibaya, ọmọ Seraaya, ọmọ Asieli.

36. Elioenai, Jaakoba, ati Jeṣohaya; Asaya, Adieli, Jesimieli ati Bẹnaya;

Kronika Kinni 4