Kronika Kinni 4:33 BIBELI MIMỌ (BM)

àwọn ìlú marun-un pẹlu àwọn ìgbèríko tí ó yí wọn ká títí dé ìlú Baali. Àwọn agbègbè náà ni wọ́n ń gbé, wọ́n sì ní àkọsílẹ̀ ìdílé wọn.

Kronika Kinni 4

Kronika Kinni 4:26-35