Kronika Kinni 4:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Etamu ni: Jesireeli, Iṣima, ati Idibaṣi. Orúkọ arabinrin wọn ni Haseleliponi.

Kronika Kinni 4

Kronika Kinni 4:2-4