Kronika Kinni 4:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣimei bí ọmọkunrin mẹrindinlogun ati ọmọbinrin mẹfa. Ṣugbọn àwọn arakunrin rẹ̀ kò bí ọmọ pupọ, bẹ́ẹ̀ ni ẹ̀yà rẹ̀ kò pọ̀ bí ẹ̀yà Juda.

Kronika Kinni 4

Kronika Kinni 4:19-28