Kronika Kinni 4:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣela, ọ̀kan ninu àwọn ọmọ Juda, ni baba Eri, baba Leka. Laada ni baba Mareṣa, ati ìdílé àwọn tí wọ́n ń hun aṣọ fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ funfun ní Beti Aṣibea

Kronika Kinni 4

Kronika Kinni 4:20-23