Kronika Kinni 4:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Iṣiba ni baba Eṣitemoa. Meredi tún ní iyawo mìíràn, òun jẹ́ ará Juda, ó bí ọmọkunrin mẹta fún un: Jeredi, baba Gedori, Heberi baba Soko, ati Jekutieli, baba Sanoa.

Kronika Kinni 4

Kronika Kinni 4:16-23