Kronika Kinni 4:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Àwọn ọmọ Juda ni: Peresi, Hesironi, Kami, Huri, ati Ṣobali.

2. Ṣobali ni ó bí Reaaya. Reaaya sì bí Jahati. Jahati ni baba Ahumai ati Lahadi. Àwọn ni ìdílé àwọn tí ń gbé Sora.

Kronika Kinni 4