Kronika Kinni 3:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní Heburoni, níbi tí Dafidi ti jọba fún ọdún meje ati ààbọ̀, ni wọ́n ti bí àwọn mẹfẹẹfa fún un.Lẹ́yìn náà, Dafidi jọba ní Jerusalẹmu fún ọdún mẹtalelọgbọn.

Kronika Kinni 3

Kronika Kinni 3:1-14