Kronika Kinni 3:15-17 BIBELI MIMỌ (BM)

15. Orúkọ àwọn ọmọ Josaya mẹrẹẹrin, bí wọ́n ṣe tẹ̀lé ara wọn ni: Johanani, Jehoiakimu, Sedekaya ati Ṣalumu.

16. Jehoiakimu bí ọmọ meji: Jekonaya ati Sedekaya.

17. Àwọn ọmọ Jehoiakini, ọba tí a mú lẹ́rú lọ sí Babiloni nìwọ̀nyí: Ṣealitieli,

Kronika Kinni 3