Kronika Kinni 29:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn tí wọ́n ní òkúta olówó iyebíye ni wọ́n mú wọn wá tí wọ́n fi wọ́n sí ibi ìṣúra ilé OLUWA, tí ó wà lábẹ́ àbojútó Jehieli ará Geriṣoni.

Kronika Kinni 29

Kronika Kinni 29:6-13