Kronika Kinni 29:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀mí rẹ̀ gùn, ó lọ́rọ̀, ó sì lọ́lá, ó sì di arúgbó kàngẹ́kàngẹ́ kí ó tó kú, Solomoni ọmọ rẹ̀ sì jọba lẹ́yìn rẹ̀.

Kronika Kinni 29

Kronika Kinni 29:20-30