Kronika Kinni 29:25 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA gbé Solomoni ga lójú gbogbo àwọn ọmọ Israẹli, ó sì fún un ní ọlá ju gbogbo àwọn ọba tí wọ́n ti jẹ ṣáájú rẹ̀ ní Israẹli.

Kronika Kinni 29

Kronika Kinni 29:17-27