Kronika Kinni 29:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Solomoni jókòó lórí ìtẹ́ OLUWA gẹ́gẹ́ bí ọba, dípò Dafidi, baba rẹ̀. Solomoni ní ìlọsíwájú, gbogbo àwọn eniyan Israẹli sì ń gbọ́ tirẹ̀.

Kronika Kinni 29

Kronika Kinni 29:17-25