Kronika Kinni 28:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn, Ọlọrun sọ fún mi pé, kì í ṣe èmi ni n óo kọ́ ilé fún òun, nítorí pé jagunjagun ni mí, mo sì ti ta ẹ̀jẹ̀ pupọ sílẹ̀.

Kronika Kinni 28

Kronika Kinni 28:1-10